Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ilé ìfowópamọ́,òsìsẹ́ ìjọba, ilé ìwòsan ,kọ etí ikún sí ìyansẹlódì ẹgbẹ́ òsìsẹ́ NLC nílùú Abùjá

0 322

Bí ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà (NLC) Se bẹ̀rẹ̀ ìwọ́de ọlọ́jọ́ méjì wọn láti fi se ìkìlọ̀ fún ìjọba àpapọ̀.
Síbẹ̀, púpọ̀ nínú àwọn ilé ìfowópamọ́ tó wà nílùú Abùjá ló ń bá isẹ́ wọn lọ pẹrẹu láìsí ìdíwọ́.lára àwọn ilé ìfowópamọ́ náà ni Zenith Bank.Titan Bank.Stanbic Ibt. platinum Bank abbl.

Bákan náà ni gbogbo àwọn ilé -isẹ́ ìjọba tó wà nílùú Abùjá  àti àwọn ilé -ìwòsàn náà wà ní sísí sìlẹ̀ tí àwọn òṣìṣẹ́ sí ń bá isẹ́ wọn lọ ni pẹrẹu bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ̀ba kéréje ní àwọn ènìyàn tó wá síbi iṣẹ́ lónìí yíì.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button