Take a fresh look at your lifestyle.

A ó fi ọwọ́ òfin mú ẹni tó kọ́ ilé tó wó yíì.- Wike

0 218

Mínísítà fún ìlú Abùjá.Nyenson Wike ti ni gbogbo àwọn ilẹ tí wọ́n kò lónà àìtọ̀ àti èyí tí kó bófinmu ni wọn yóò wulẹ̀.

Òún yóò sì rí I pé ètò ìlànà ilé kíkọ́ ni àwọn tó ń ki ilé sí ilú Abùjá tẹ̀lé.
Wike sọ̀rọ̀ yìí lásìkò tó wá sí agbègbè Garki tó wà nílùú Abùjá níbi tí Ilé alájà méjì tó wó lulẹ̀ náà.
Wike ni òun yóò ri i pé won fi ọwọ́ òfin mú ẹni tó kọ́ ilé ọ̀hún.


Bákan náà nì àwọn yóò ṣe ìwádìí nipa ìsẹ̀lẹ̀ ọ̀hún.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button