Ààrẹ Zimbabwe, Emmerson Mnangagwa, tó tún jẹ adari ẹgbẹ́ òṣèlú tó ń ṣàkóso lọwọ́, Zanu-PF ti di ibò rẹ̀ bi ibò ti ń lọ lọwọ́ ni orílẹ̀-èdè Zimbabwe ní ọjọ́ Ọjọ́rú.
Ó dìbò pẹ̀lú obìnrin àkọ́kọ́, Amai Dr Auxillia Mnangagwa ni ile ìwé alakobere Sherwood Park ti ìlú Kwekwe
Àwọn ènìyàn mọ́kànlá ló ń dìje pẹ̀lú ọmọ ọgọ́rin ọdún ààrẹ tó ń ṣàkóso lọ́wọ́ pẹ̀lú alátakò rẹ̀ ọmọ ọdún màrúndín laáàdọ̀ta-Nelson Chamisa, tó jẹ́ adari ẹgbẹ́ òṣèlú Citizen’s Coalition for Change (CCC).
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply