Ààrẹ Bọla Tinubu ṣèpàdé pẹ̀lú gómìnà Peter Mbah ti ìpínlẹ̀ Enugu, ní ilé iṣẹ́ ààrẹ Villa, Abuja.
Lẹyin ipade naa ti awọn oniroyin fẹ baa sọrọ, ko fesi kankan.
Ṣugbọn ifọrọjomitoro ọrọ oun ati aarẹ ko le ja lori idagbasoke ati eto aabo ipinlẹ Enugu.
Bi Gomina Mbah ṣe gori oye ni o ti fi han si awọn eniyan pe oun fẹ yi ẹka ijọba pada si ẹka ọrọ aje aladaani nipasẹ idokowo ọrọ aje ẹka aladani.
Nigba ti gomina Enugu sabẹwo si aarẹ kẹyin, o ba aarẹ sọrọ lori aarẹ awọn eniyan ti Biafra, IPOB, Nnamdi Kanu ati itusilẹ rẹ ninu tubu.
Leave a Reply