Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ BATS-V Gbóríyìn Fún Ààrẹ Tinubu Fún Yíyàn Àwọn Kọmísọ́nà Àti Àwọn Abáni Ṣiṣẹ́ Pọ̀ Rè 

0 200

Ẹgbẹ́ ti wọn pè ní Solidarity Vanguard (BATS-V) ti Gbóríyìn fún Ààrẹ Tinubu fún yíyàn to àwọn Mínísítà ti wọn ṣe àyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ni ilé igbimọ aṣofin.

Nínú ọ̀rọ̀ atẹjade kan láti ọwọ́ Simeoni Anayo Anyachie to jẹ olùdámọ̀ràn pàtàkì  lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn fún ẹgbẹ́ náà àti alága fún ẹgbẹ́ náà Dare Owotombi sọ wí pé Ààrẹ Tinubu ṣe dada nípa yíyan to àwọn Mínísítà ti yóò mú iṣé ìjọba rẹ yà.

Wọn ní yíyan náà dun mọ àwọn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ninu gidigidi pẹlu ìrètí wí pé yóò mú àṣeyọrí ba ijoba Ààrẹ Tinubu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button