Take a fresh look at your lifestyle.

PEPT: Ẹgbẹ́ Kan Kìlọ̀ Fún Àwọn Olóṣèlú Láti Má Sọ̀rọ̀ Òdì Sí Àwọn Adájọ́

0 192

 

Egbé kan tó sàtìlẹyìn fún àwọn olóṣèlú ní ìbò ààrẹ ti ọdún 2023 Bola Campaign Organisation (BCO), ti rọ àwọn olósèlú.


láti má ṣe sọ ọ̀rọ̀ àlùfànsá tàbí ọ̀rọ̀ àbùkù sí àwọn adájọ́ tó wà nípa ti Presidential Election Petition Tribunal (PEPT) , ọ̀rọ̀ òṣèlú.

 

Àjọ BCO sọ èyí láti ẹnu bàbá ìsàlẹ̀ àpapọ̀, Alhaji Abdulwahab Korede Quardi (FCIB) àti Olùdarí àpapọ̀ , QS Mohammed Makinta (FNIQS).

 

Ẹgbẹ́ náà sọ pé, ó yẹ ki wọ́n fi ètò èka ìdájọ́ sílẹ̀ kí wọ́n se isẹ́ wọn, kí wọ́n má ṣe fi àyè gba àwọn onísokúsọ tó leè yọ àwọn adájọ́ lẹ́nu láti se isẹ́ wọn bí iṣẹ́. Àjọ BCO tún rọ àwọn adájọ́ náà láti ṣe ìdájọ́ òdodo, bí wọ́n ti ń retí láti ọ̀dọ̀ ajo
presidential elections petition tribunal (PEPT), láti gbé èsì ìdájọ́ jáde ní oṣù kẹsàn án.

 

 

Temitope Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button