Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano Ráwọ́ Ẹ̀bẹ̀ Fún Ìrànlọ́wọ́ Tetfund

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 196

Gómìnà Abba Yusuf tí Ìpínlẹ̀ Kano tí ráwọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àjọ “Tertiary Education Trust Fund TETFUnd” látí tún bọ̀ tèsíwájú lórí iṣẹ́ wọ́n ní Yusuf Maitama Sule University àtí Kano University of Science and Technology, Wudil.

Gómìnà, ráwọ́ ẹ̀bẹ̀ náà ní ìlú Abuja làkókò tó ṣé àbẹwò sí Àkọwé àgbà tí TETFUnd, Ọ̀gbẹ́ni Sonny Echono, ṣé àfihàn ìwúlò fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tó lágbára láàrín ijọba ìpínlẹ̀ Kano àtí TEtFund látí ríi dájú pé ìlọsíwájú ètò ẹ̀kọ́ ní ìpínlẹ̀ náà.

Làkókò tó ń yin TETFund fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn iṣẹ́ àmàyédẹ̀rún rẹ̀ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga ní gbogbo orílẹ̀-èdè, Gómìnà ní pàtàkì pé fún àtìlẹ́yìn TETFUnd ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga méjì ní àwọn àgbègbè ìpèsè àwọn òun èlò síi, ikẹkọ àti àtúnṣe àwọn òṣìṣẹ́ pẹ̀lú ìṣàkóso omíyalé ní Kano University of Science and Technology, Wudil.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button