Sẹnẹtọ Solomon Adeola Olamilekan tí jẹ Alága Ìgbìmọ̀ Aṣòfin àgbà lórí ètò ìpín owó.
Ààrẹ Sẹnetọ̀ Nàìjíríà, Godswill Akpabio ló kéde èyí ní ọjọ́ àbámẹ́ta nígbà tó ń dá ìgbìmọ̀ yíyan fún Sẹnetọ̀ sílẹ̀ lábẹ́ ìdarí rẹ̀, pẹ̀lú igbákejì rẹ̀, Jubrin Barau gẹ́gẹ́ bí igbákejì alága ìgbìmọ̀ yíyan.
Sẹnẹtọ Mohammed Ali Ndume ní wọ́n yán gẹ́gẹ́ bi Ìgbákejì Alága tí Ìgbìmọ̀ náà, lẹyìn ipò rẹ̀ bi “Chief Whip.”
Àlàyé lẹkunrẹrẹ mbọ̀ láìpẹ́…
Leave a Reply