Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Tí Ṣé Tán Láti Fi Orúkọ Àwọn Onífẹ̀yìntì Sílẹ̀ Fún Ètò Ìlera Ìpínlẹ̀ Náà

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 448

Gómìnà Ademola Adeleke tí Ìpínlẹ̀ Osun tí kéde pé àwọn òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì ní ìpínlẹ̀ náà yóò ní ànfààní nínú ètò iṣeduro ìlera ní Osun.

Adeleke ṣé ìtọ́kasí yìí làkókò tí o ngbà àwọn aṣáájú kàn ní àlejò fún ọdún Iléyá ní ilé rẹ̀ ní Ede.

Gómìnà ṣàlàyé pé ìṣàkóso rẹ̀ ti n ṣètò láti kojú italaya ètò ìlera fún àwọn òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì lójúnà àtí fí wọ́n kún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìpínlẹ̀ náà.

O tẹnumọ pé ìjọba Òun mọ́ pàtàkì àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba, ìdí ní yí tí ìgbìyànjú ìrànlọ́wọ́ rẹ̀ fún àwọn òṣìṣẹ́ àtí àwọn òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì fí jẹ́ òún lógún.

Bẹ́ẹ̀ ló tún fí kún pé ní ì o.f.kbEọdún yìí ní òún tí buwọ́lù ètò láti sàn gbogbo owó oṣù àwọn òṣìṣẹ́ àti àwọn òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì tí wọ́n jẹ́ wọ́n sẹ́yìn.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button