Take a fresh look at your lifestyle.

Eid-Al-Adha: Àwọn Àjọ Kàn Ṣé Ìtọrẹ́ Oúnjẹ Fún Àwọn Obínrin Aláìní Ní Abuja

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 359

Ó jú ọgọrùn lé lọgọ́ta àwọn Obìnrin aláìní ní Olú-ìlú Nàìjíríà, Abuja, tó jẹ́ ànfààní oúnjẹ tí àjọ Federal Capital Territory Management Agency (FEMA), ati NEAR Foundation (àjọ tí kìí ṣé tí ìjọba) pèsè, nínú ajọyọ Eid-Al-Adha.

Làkókò tó ń fí ẹbùn náà tọrọ́, Olùdarí Gbogbogbò tí FEMA, Dókítà Abbas Idris sọ pé ìnáwọ́sí náà wá làti mú inú gbogbo wọ́n fún ayẹyẹ ọdún iléyá.

Olùdarí Gbogbogbò náà tí Engr. Abdul Rahman Mohammed, Oludari Relief and Rehabilitation of the Agency ṣoju rẹ̀, rawọ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn Mùsùlùmí látí fáráwé NEAR Foundation látí máa ṣé ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tó nílò rẹ̀.

Halita Joseph ati Samuwa Yohana tó ṣójú àwọn IDP ní Waru, Yimutu àti Malaysia Garden dúpẹ púpọ fún àwọn ẹbùn náà, wọ́n sì rọ̀ ìjọba àpapọ̀ láti pèsè ayé fún kíkọ́ iṣẹ́ ọwọ́.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button