Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Osun State Government

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Tí Ṣé Tán Láti Fi Orúkọ Àwọn Onífẹ̀yìntì Sílẹ̀ Fún Ètò Ìlera Ìpínlẹ̀ Náà

Gómìnà Ademola Adeleke tí Ìpínlẹ̀ Osun tí kéde pé àwọn òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì ní ìpínlẹ̀ náà yóò ní ànfààní nínú ètò iṣeduro ìlera ní Osun. Adeleke ṣé ìtọ́kasí yìí làkókò tí o ngbà àwọn aṣáájú kàn ní àlejò fún ọdún Iléyá ní ilé rẹ̀ ní Ede.…

Ètò Ìdìbò Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Osun Kéde Ìsìnmi Lẹ́nù-iṣẹ́ Ọjọ́ Ẹtì

Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke tí kéde ìsinmi lọjọ́ Ẹtì ṣáájú ètò ìdìbò ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ náà tí yóò wáyé ní ọjọ́ Ẹtì. Èyí wà nínú àtẹ̀jáde tí agbẹnusọ Gómìnà, Mallam Olawale Rasheed sọ́ fún òníròyìn VON ní Osogbo…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Osun Ṣé Ìdánilójú Ìgbéga Ilé-ìwé Gíga Iléṣà

Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke sọ pé Yunifásítì túntún Iléṣà tí fí ìdí múlẹ̀ àtí pé iṣẹ́ àtúnṣe rẹ̀ tí bẹ̀rẹ̀ báyìí. Gómìnà ṣàlàyé èyí ní ọjọ́ Ẹtì ní Iléṣà làkókò àbẹwò lẹ́nú iṣẹ́ sí ilé-ẹ̀kọ́ náà látí ṣàyẹ̀wò àwọn òun èlò…
button