Take a fresh look at your lifestyle.

Á Tí Ṣétán Láti Ṣé Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú DSS Lórí Ètò Ààbò – NSCDC

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 325

Nigeria Security Civil Defence Corps, NSCDC, àtí Department of State Services, DSS, tí ṣé àdéhùn ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí pínpín òye fún ètò ààbò, ààbò ẹ̀mí àtí oun-ìní ní Ìpínlẹ̀ Anambra.

Èyí ló di mímọ nígbà tí ọgá àgbà NSCDC túntún ní ìpínlẹ̀ Anambra, Edwin Osuala, ṣé àbẹ̀wò sí ọfisi DSS ní ìpínlẹ̀ náà.

Gẹ́gẹ́ bí àlàyé tí Àlùkòrò Ilé-iṣẹ́ NSCDC, DSC Okadigbo Edwin sọ́ pé Alákóso Osuala tí Olùdarí tí ẹṣọ ààbò Ìpínlè DSS, Ọ̀gbẹ́ni Enoch Pawa gbà ní àlejò, sọ pé ìdí àbẹ̀wò rẹ̀ ní láti só ìbáṣepọ̀ tó wà láàrín àjọ méjèèjì tẹlẹ lé.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button