Á Tí Ṣétán Láti Ṣé Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú DSS Lórí Ètò Ààbò – NSCDC
Nigeria Security Civil Defence Corps, NSCDC, àtí Department of State Services, DSS, tí ṣé àdéhùn ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí pínpín òye fún ètò ààbò, ààbò ẹ̀mí àtí oun-ìní ní Ìpínlẹ̀ Anambra.
Èyí ló di mímọ nígbà tí ọgá àgbà NSCDC túntún ní…