Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Faransé Kìlọ Fún Iran Lórí Fífi Drone Ránṣẹ́ Sí Russia

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 225

Ààrẹ Faransé Emmanuel Macron tí kìlọ fún Ààrẹ Iran Ebrahim Raisi nípa ìpàdábọ̀ àwọn ọkọ ìjà ofurufu (Drone) rẹ̀ tó fí ń ránṣẹ́ sí Russia.

Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ Faransé náà sọ nínú àlàyé kàn pé Ààrẹ Macron rọ́ Ààrẹ Iran látí dẹkùn àtìlẹ́yìn tó ń fún Russia nínú ogún Ukraine ní kíákíá.

Tún kà nípa:Orílẹ̀-èdè Russian Fi Ẹ̀sùn Kan Orílẹ̀-èdè U.S Lórí Ríran Àwọn Orílẹ̀-èdè Ukraine Lọ́wọ́ Láti Gbógun Tì Wọ́n.

Britain, Faransé, Germany, America àti Ukraine sọ pé ìpèsè àwọn òun ìjà lòdì sí òfin Ìgbìmọ̀ Ààbò Àgbáyé (UN Security Council) 2015 tó fí ayé ṣí ṣé àwọn òun ìjà yìí ní Iran

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button