Take a fresh look at your lifestyle.

Ọmọ Ọba Jerry Ṣetan Láti Fi Ẹrí Hàn Ní Ilé Ẹjọ́ Ni Ìlú London.

0 216

Ọmọ ọba Harry ṣetán láti farahàn ni ilé ẹjọ́ to wà ní London ni ọjọ́ ajé, pẹ̀lú ẹrí lati Tako onkọwe Orílẹ̀-èdè British ti Daily Mirror.

Harry, Tó jẹ̀ ọmọ ọba Charles ni yóò jẹ ọmọ ọba àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè British ti yóò fí ẹrí kalẹ ní ilé ẹjọ́ láti ọgọrùn ọdún ò lè ọgbọn.

Ìpẹ̀jọ́ bẹ̀rẹ̀ ní oṣù to kọjá nígbà tí àwọn agbẹjọ́rọ̀ fún ọmọ ọba Harry ati àwọn mẹta míràn ṣetán láti fi àwọn gbógì ẹrí hàn ni ilé ẹjọ́.

Tí ọ̀sẹ̀ ni yóò di elekeji ti wọn yóò ma fi ará hàn ní ilé ẹjọ́.

Onkọwe yìí ni o ti kò pa ninu àwọn ìwà ìbàjẹ́ pẹ̀lú awọn oníròyìn ní Orílẹ̀-èdè British ati fífi ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ ṣiṣẹ́ ìbàjẹ́.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button