Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ EFCC Bèrè Fún Ìbaṣepọ̀ Láti Ṣe Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Lórí Ìwà ìbàjẹ́ Nípa Owó.

0 240

Àjọ tó mójú tó ọ̀rọ̀ ṣiṣe owó ìlú kúmọkùmọ EFCC, tí pé fún ìbáṣepọ̀ àwọn oníròyìn láti lè ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà ìbàjẹ́ tó wà ní ṣíṣe owó ìlú kúmọkùmọ.

Aláṣẹ àti alága fún àjọ náà , Ọ̀gbẹni Abdulrasheed Bawa sọ èyí di mímọ̀ níbi ìpàdé àwọn oníròyìn nipa ṣíṣe owó ìlú kúmọkùmọ ni ìpínlẹ̀ Sokoto.

Alága fún àjọ náà ní ètò je àǹfààní láti jẹ kí àwọn ènìyàn àbùkù nípa ṣíṣe owó ìlú kúmọkùmọ.

O wà rọ àwọn ará ìlú láti rí wí pé wọn gbìyànjú agbára wọn kì ìwà ṣiṣe owó ìlú kúmọkùmọ di àfìsẹ́yìn.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button