Awọn oṣiṣẹ àjọ tó ń gbógun ti ṣíṣe owó ìlú kúmọ-kùmọ lórílèdè Nàíjíríà EFCC, ti mu awọn olura ibo meji ti wọn fẹsun kan ni Gusau, Ipinlẹ Zamfara, ẹkùn Àríwá orílẹ̀-èdè Nàíjíríà.
Agbẹnusọ fun Igbimọ náà Ọgbẹni Wilson Uwujaren ṣe afihan eyi nínú àtẹ́jáde kan ni Abuja.

Ó ní ọwọ́ ba Mustapha Abubakar pẹ̀lú owó tó tó ọ̀kẹ́ mẹ́jọ ààbọ̀ Naira (170,000) pẹlu tikẹti ti wọn ṣe fun awọn oludibo gẹgẹ bi ẹri fun ibo ẹgbẹ rẹ ṣaaju gbigba owo náà.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply