Take a fresh look at your lifestyle.

Akọrin àti olóṣèlú, Banky W gbóríyìn fún ètò ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Èko

0 332

Ọ̀kan lára àwọn olùdíje tí ó tún jẹ́ gbajúgbajà akọrin, Bánkọ́lé Wellington, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Banky W, fi èróngbà rẹẹ̀ hàn lórí ètò ìdìbò Ààrẹ àti ti ilé ìgbìmọ̀ asòfin, ọdún 2023.

Àwọn olùdánilárayá pitú nínú ìdìbò gbogbogbòò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ọdún 2023, Ìdìbò yìí yatọ sí àtẹ̀yìnwá.

Akọrin ọ̀hún ń dupò aṣojú ṣòfin ní ilé ìgbìmọ̀ aṣojú agbègbè Etí-Ọ̀sà lápapọ̀ ti ìpínlẹ̀ Èkó, ìgbà kejì rẹẹ̀ nìyí tí yò dupò náà.

Inú rẹ̀ dùn fún bí àwọn olùdìbò ṣe tú yáyá, tú yàyà jáde fún ìdìbò àti ètò ìlànà ìdìbò náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button