Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò tẹ̀síwájú lónìí, ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n, oṣù kejì ní Ìpínlẹ̀ Cross-River

0 226

Àjọ elétò ìdìbò (INEC), ti sún ìdìbò Ààrẹ àti ti ilé ìgbìmọ̀ asòfin sí ọjọ́ àìkú, ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì, ọdún 2023 ní ìjọba ìbílẹ̀ Bakassi ní Ìpínlẹ̀ Cross River, ẹkùn gúsù-gúsù  orílẹ̀-èdè Nàíjíríà.

Àtẹ́jáde kan tí Olórí Ẹ̀ka, Ẹ̀kọ́ Àwọn olùdìbò àti Ìpolongo, Anthonia Nwobi fọwọ́ sí ní orúkọ Kọmísọ́nà Ìdìbò olùgbé, Ọ̀jọ̀gbọ́n Gabriel Yomere tọ́ka sí pé àwọn agbègbè níbi tí ìdìbò kò wáyé ní ọjọ́ Sátidé, Oṣù kejìlá ọjọ́ karundinlọgbọn ni wọ́n sún sí ọ̀ní ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì, ọdún 2023.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button