Take a fresh look at your lifestyle.

Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Dìbò Ní Ìlú Èkó

0 218

Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìlú Abuja, Fẹmi Gbajabiamila ti dìbò ní ibùdó ìdìbò Ilé-ìwé alákọ̀bẹ́rẹ̀ẹ̀ Elizabeth Fowler, Masha- Suurulere.

 

Ó sọrọ ní déédé agogo mọ́kànlá òwúrọ̀ ọjọ́ Àbámẹ́ta nígbà tí ó dìbò tán. Ó sàlàyé pé ètò náà lọ ní ìrọwọ́-rọsẹ̀.

 

Gbajabiamila wá fi àfojúsùn rẹ̀ hàn pé, ètò náà yóò kẹ́sẹ járí jákè-jádò Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button