Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari ti dìbò

0 232

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti dibo níbi eto idibo Ààrẹ àti ti Ile-igbimọ orilẹ-ede, ọdún 2023.

Ọmọ orilẹ-ede Naijiria akọkọ dibo ni bii aago mẹsan aarọ ni bi idibo Kofar Baru 003 ti Sarkin Yara ‘A’ ti Daura, ni ijọba ibilẹ Daura ni ipinlẹ Katsina.

Oun ati iyawo rẹè Aisha ni wọn jọ lọ dibo naa.

Inu awọn ọmọ ipinlẹ Katsina dun nigba ti aarẹ balẹ̀ si ibi idibo náà

 

Ọláyinká Akíntọ́lá

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button