Ẹgbẹ́ Òsèlú New Nigeria People’s Party (NNPP) ti sẹ́ àhesọ ọ̀rọ̀ pé wọ́n ti lọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òsèlú People’s Democratic Party látàrí ìbò ọdún tó ń bọ̀.
Ẹgbẹ́ rọ àwọn ènìyàn láti má tẹ́tisílẹ̀ sí kùbákùngbé ọ̀rọ̀ náà wípé kosi nkàn tó jọọ́.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply