Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ APC Ìpínlẹ̀ Kwara Fọwọ́sí Àwọn Olórí Ẹgbẹ́ Tuntun

125

Àwọn Olórí ẹgbẹ́ òṣèlú ‘All Progressives Congress APC’ ti Ìpínlẹ̀ Kwara ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, tún gbá àṣẹ láti tẹ̀síwájú ṣe olórí jákèjádò Ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rindínlógún pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ gbogbo ọmọ ẹgbẹ́.

‎ Ìgbésẹ̀ náà, èyítí o fa àwọn olórí ẹgbẹ́ àti àwọn olóyè ní ọ̀pọ̀ yanturu jade pẹ̀lú àlàáfíà ní Ìpínlẹ̀ náà.

‎Awọn olórí ẹgbẹ́ àpapọ̀ ẹgbẹ́ APC, pẹ̀lú Alága ẹgbẹ́ náà ní Ìpínlẹ̀ Kwara, Alhaji Abdullahi Samari àti àwọn àgbà ẹgbẹ́ mìíràn.

Comments are closed.

button