Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ NAF Sí Pápákọ̀ Òfurufú Ti ìpínlẹ̀ Kaduna Láti Ipàlẹ̀mọ́  Fún Ìdanilẹ́kọ̀ọ́ Ọkọ̀ Òfurufú Ti Yóò Wáyé.

65

Ẹgbẹ́ Ọmọ-ologun Afẹ́fẹ́ Nàìjíríà (NAF) ti gbé ìgbésẹ̀ pàtàkì láti ni imura sílẹ̀ iṣẹ́ wọn fún ọkọ̀ òfurufú ìran tó ń bọ̀ pọ̀ sí i nípa ṣíṣe àwọn ètò ìṣiṣẹ́ pàtàkì ní NAF ti ìpínlẹ̀ Kaduna láti mú kí ìdanilẹ́kọ̀ọ́ àti imura sílẹ̀ àwọn òṣìṣẹ́ wọn pọ̀ sí i.

Níbi ayẹyẹ náà ní ọjọ́ Ẹtì ni Olórí Ọkọ̀ Òfurufú, CAS, Air Marshal Sunday Aneke  ti sọ wí pé àwọn ìdàgbàsókè náà ṣe pàtàkì láti múra sílẹ fún àwọn ìran àwọn awakọ̀ òfurufú tuntun  tí ń bọ̀ fún Iṣẹ́ náà.

Ẹgbẹ́ CAS fi ìmọ rírì wọn hàn sí Ààrẹ àti Olórí Ọkọ̀ Òfurufú, Ààrẹ Bola Tinubu, fún ìdúróṣinṣin rẹ̀ sí ààbò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ó mọ rírí ise ọgá àgbà tẹ́lẹ̀ rí, Air Marshal HB Abubakar fún òye tí ó ní nípa ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà, ógbóríyìn fún Ẹ̀ka Àwọn Ohun Èlò, Olùdarí Ọkọ̀ Òfurufú, àti gbogbo àwọn oníṣẹ́ fún ìmuṣẹ àwọn iṣẹ́ náà ní àkókò tó yẹ.

Comments are closed.

button