Take a fresh look at your lifestyle.

Ipinlẹ̀ Ebonyi Gba Ìwé Ẹ̀rí Láti Jẹ́ Kí Ọkọ̀ Òfúrufú Leè Máa Ṣisẹ́

16

 

Ìjọba Ipinlẹ Ebonyi ti sọ pé àwọn ti rí Ìwé Ẹri gba láti leè jé kí Ọkọ Ofurufu tiwọn leè máa síṣe, otitọ ní wọn ti gbàá o ti wà nilẹ.

Kọmísánà fún ọkọ ofurufu àti ìmọ ẹrọ Ìrìn-àjò, Ngozi Obichukwu lọ sọ èyí fún àwọn oníròyìn.

Eléyìí wáyé ní kété ti wọn kò àwọn Ọ̀dúnrún ún ènìyàn lọ sí ilẹ Yúrópù àwọn tó jẹ anfààní ètò scholarship ní Pápákọ̀ òfurufú agbaye Chuba Okadigbo, Onueke ipinlẹ Ebonyi.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button