Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ NECA Ati NSIFT Bèrè Fún Agbègbè Isẹ́ Tó Ní Ààbò Tó Péye.

77

Ẹgbẹ́ ètò ìṣura NSIFT ati ẹgbẹ́ to n gbà ni ṣi iṣẹ́ NECA bèrè fún agbegbe  ti yóò ni ààbò nínú fún àwọn òṣìṣẹ́

Níbi ayẹyẹ ọlọdún ti o ma n wáyé mi ìlu Abuja ni ọ̀rọ̀ náà ti jáde.

Ajo SWIP ni ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ méjèjì yìí ti èròngbà wọn sì jẹ láti mú ìdàgbàsókè bá àsà wa, ìlera àti agbègbè to péye fún iṣé.

Níbi ayẹyẹ náà ni ẹgbẹ́ mejilelọgbọn ló gbà ààmì ẹ̀yẹ.

Nigbati Adari ẹgbẹ́ NSIFT n ba àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ náà Ọ̀gbẹni Olúwaṣeun Falaye sàlàyé pàtàkì ti o wa nínú ààbò to péye wí pè o jẹ ohun ẹ̀tọ́ fún àwọn ènìyàn báyìí láti ni agbègbè to ye koro

Ó wa pe gbogbo agbaye láti ri wí pè o tona ki àwọn agbani sí iṣẹ́ ṣe eto ààbò to péye fún ìdàgbàsókè àti ìtèsíwájú àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ó ki àwọn aṣojú níbi Ìpàdé náà ku Orire, bákanáà ọ rọ wọn ki wọn jẹ aṣoju réré ni enu ìṣẹ́ wọn.

Comments are closed.

button