Lẹyìn ayẹyẹ ìdíje bóòlù aláfesẹ̀gbà ti Orílẹ̀-èdè Áfíríkà ti Orílẹ-èdè Morrocco gbalejo rè, níbè ni Olórí Agbábóòlù Orílè-èdè Senegal Mene ti ààmì ẹ̀yẹ Agbábóòlù to dángájíá jùlọ ti Odún 2025.
Olórí Agbábóòlù Orílè-èdè Senegal Mene cemented ti gbà ààmì ẹ̀yẹ fún ìgbà Kejì. Mene cemented gbà Ààmì Ẹ̀yẹ Bóòlù Òní góòlù ni ọdun 2022.
Ìdíje bóòlù náà gbóná pùpọ́ láàrin Orílè-èdè méjèjì ṣùgbón pẹ̀lú akitiyan Mene wọn borí ẹgbẹ́ Orílè-èdè Morrocco.
Ìròyìn ni àwọn ènìyàn míràn náà ni anfààní láti gbà àmì ẹyẹ ni àwọn ẹka míràn.
Bákannáà Yassine ni o gbà ààmì ẹ̀yẹ amu bóòlù oju ile .