Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-iṣẹ́ ‘Galaxy Backbone’ Tí Ṣetán Lati Ṣayẹyẹ Ogún Ọdún ‎

93

‘Galaxy Backbone Limited’ (GBB), ilé-iṣẹ́ Ayélujára tó ga jùlọ ní Nàìjíríà àti olùpèsè iṣẹ ayélujára tí Ìjọba Àpapọ̀ tí kéde ayẹyẹ ogún ọdún ilé-iṣẹ́ náà tí yóò wáyé ní Oṣu Kẹfa ọdún 2026.

‎Èyí ni a sọ ninu atẹjade kan ti Olori Ìròyìn àti ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ti Ilé-iṣẹ́ náà, Chidi Okpala, fọwọ́ sí.

‎ Gẹgẹ bí O ti sọ, ipá pàtàkì náà yóò sami ogun ọdun tí dá ilé-iṣẹ́ náà sílẹ̀ ní ọdún 2006 pẹ̀lú àṣẹ nlá láti ọdọ Ìjọba Àpapọ̀.

‎Ikede náà wa lẹyìn ọdún 2025 tí ile-iṣẹ náà ṣaṣeyọri púpọ. Ni oṣù to kọjá, GBB gbá ipò àkọkọ́ láti ọdọ Ìjọba Àpapọ̀, nínú ìwé àwọn ilé-iṣẹ́ ayélujára tí dára jùlọ tí ọdún 2025, èyí tí ile-iṣẹ aṣeṣiro ti Orílẹ̀-èdè yí gbé kalẹ̀ (Bureau of Public Service Reforms BPSR).

Comments are closed.

button