Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Tún Fi Ìdúróṣinṣin Ìjọba Rẹ̀ Hàn Sí Ìgbésẹ̀ Ojúọjọ́ Ní Ìpàdé Abu Dhabi

145

Ààrẹ Bola Tinubu tí sọ̀rọ̀ ní ìpàdé àgbáyé Abu Dhabi ti ọdún 2026, ó sì tẹnu mọ́ ìdúróṣinṣin Nàìjíríà sí ìgbésẹ̀ ojúọjọ́ àti ìdàgbàsókè tó ṣeé gbé.

‎Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ níbi ìpàdé gíga kán ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun ní ‘Abu Dhabi National Exhibition Centre’ (ADNEC), Ààrẹ Tinubu rọ àwọn alábáṣiṣẹpọ̀ káríayé fún àtìlẹ́yìn àti láti jẹ́ àǹfààní bí bá Orílẹ-èdè rẹ̀ dowó pọ lórí ìyípadà ojúọjọ́.

‎Ó tẹnu mọ́ ìmúrasílẹ̀ Nàìjíríà láti bá àwọn alábáṣiṣẹpọ̀ káríayé ṣiṣẹ́ ní àwọn agbègbè bíi agbára àgbáayé, ọjà ìyípadà ojúọjọ́, kíkọ́ni ní àwọn ìmọ̀ ìdàgbàsókè àti ìmọ̀ sáyẹ́nsì tuntun.

Comments are closed.

button