Mínísítà fún ìlú Abuja Nyesom Wike ti pe fún ìsọ̀kan ni ìpínlè River ki ìdàgbàsókè bá Le joba ni ìpínlẹ̀ náà lásìkò ìdìbò.
Lásìkò ti o ṣe àbẹ̀wò o ṣeun modupé sí Ìjoba ìbílẹ̀ Andoni ni ìpínlẹ̀ River ni ọ̀rọ̀ náà ti jáde.
Ó ní ìsọ̀kan yóò mu ìdàgbàsókè bá ìjoba ìbílẹ̀ Andoni ati àwọn ènìyàn ibẹ̀.O ni o ṣe pàtàkì fun àwọn adari láti wa nínú ìṣọ̀kan.
Bákanáà ọ gbà àwọn ènìyàn níyànjú láti ṣiṣẹ́ pọ̀ fún ara wọn ki àlàáfíà ba jọba tó láàrin ilu.
Mínísítà ni awọn olóṣèlú ti o wa ni ìpínlẹ̀ River wa ni abẹ àsìá ti wọn pé ni ìrètí fún ẹbi èyí ti yóò mú eto ìdìbò Ààrẹ Bọla Ahmed rọrun fún gbogbo ènìyàn.
Alága ìbílẹ̀ Ọ̀gbẹni ọmọba Otito so fún wí pè ki mínísítà wike fi okan balè pátá pátá nitori gbogbo ẹ̀tò ni o ti to fún ẹ̀tò ìdìbò ọdun 2027.
Ó wá dupẹ lọwọ wike fún àtìlẹ́yìn re àti anfààní ti o fihan fún àwọn ènìyàn