Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tú Àṣírí Àwọn Oníṣẹ́ Láabi Ni Ìpínlẹ̀ Adamawa.

266

Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti wọn n pé ni OPHK ti dènà ìwà ìbàjẹ́ ti yóò mú emi opolopo àwọn ènìyàn ló.

Ọwọ́ ba àwọn ènìyàn mẹjọ, ati àwọn odara meji  miran ni inu ọjà Gamboru ni èyí tì wọn fẹ gbà Emi ara wọn ati àwọn ènìyàn nipasẹ ado olóró.

Nínú atẹjade kan láti ọdọ ọgá àgbà Uba to jẹ agbenuso fún ikó náà so wí pè àwọn ikó náà ,  gbà ẹrọ ibanisọrọ , owó, iwe idanimọ ati àwọn ohun èlò ọlọ́rọ́.

Ó ni àwon nkán  ti àwọn gbà  wa ni amojuto àwọn báyìí.

Ò ní isé àwọn ni láti dènà Ise ibaje láàrin ilu ki àwọn sí ṣe ààbò to péye fún àwọn ará ìlú.

Comments are closed.

button