Ẹgbẹ́ Agbábóòlù Chelsea so wí pè Títí di ọdún 2032 ni Rosenior yóò fí wá ni ipo Olukọni àgbà, fun ẹgbẹ́ náà ọ̀rọ̀ yìí jade ní ọjọ́ ìṣẹgun.
Rosenior ló kó ikọ̀ Agbábóòlù Strasbourg ló ṣì Orílẹ̀-èdè European fún ìdíje ṣùgbọ́n ni báyìí o ti Gba ipò lọwọ Enzo Mares ti o fi ẹgbẹ́ Agbaboolu Chelsea sile.
Ò ní inú òun dùn gidigidi sí ipò tuntun náà láti jẹ Olùkọ agba fún ikó agbaboolu Chelsea, ti o sí pinu lati sa ipa re fún ìdàgbàsókè ẹgbẹ́ náà.