Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Ri Asia Iṣọkan

45

 

Àárín gbùngbùn ipinlẹ Kwara ti ri ásíà iṣọkan oní àádọ̀rin Mítà ní gíga ti gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq pé ìtúmọ̀ rẹ̀ ní “Iṣọkan àpapọ̀” –  “national unity”, àjọsọpọ Irinajo wà àti èròngbà wà gẹ́gẹ́ bí ènìyàn.

 

Ní ibi ìpàdé ní ilu Ilorin, Gómìnà sọ pé, ipinlẹ kò gbé àsìá sókè lásán, ṣùgbọ́n ìtumọ̀ rẹ̀ jẹ́ ìṣọ̀kan, iyì àti àmì ìdánimọ̀ àpapọ̀.

 

Kọmísọ́nà fún ètò ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, Bola Olukoju, ti Kọmísọ́nà mẹta : Aliyu Kora Sabi (Irinajo); Nafisat Buge (Ode); àti Nnafatima Imam (Ìdàgbàsókè Ìgbáyégbádùn),
míràn ran lọ́wọ́ ni wọ́n sojú fún Gómìnà.

Ọpọlọpọ gbogbo ọmọ ìpínlẹ̀ náà ló péjú pèsẹ̀ láti wòó, ọgá àgbà àwọn olopaa, DCP Nurudeen Abdulraheem, àti àwọn ènìyàn jànkàn jànkàn míràn ló wà níbi ètò náà.

” A ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà, a ní ilé ìwòsàn ìgbàlódé, a ti ró rírí omi lágbára, a sì ti rán àwọn àgbẹ̀ lọ́wọ́, onísòwò, mẹ̀kúnnùn láàrin wà láti ṣètò fún, abbl.

Àsìá yìí sọ nípa ohun tá jẹ́, ibi gíga tí à ń lọ. Ipinle Kwara ń ṣiṣẹ́, o rẹwà, àti pé gbogbo agbayé ló rí wa”, ó fi èyí kun.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button