Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ kano Buwọ́lù Lu Biliọnu Mẹta Fún Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Ti Yóò Ko Ìdánwò.

57

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti ya owó Biliọnu Mẹta sọ tọ́ láti ṣe iranlọwọ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti yóò ko ìdánwò NECO ni ọdún yìí.

Ó ní èyí wa ni ìbámu pẹ̀lú èròngbà ìjọba ìpínlẹ̀ náà láti ṣe àtìlẹ́yìn fún ètò ẹ̀kọ́ àti ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn.

Ó ní àwọn akẹ́kọ̀ọ́ káàkiri ni o tí  fi orúkọ sílè fún ìdánwò náà.

Ó ní àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti o yege ni yóò ko ìdánwò wọn Lai sí ìdádúró nínú.

Haruna rọ àwọn ọgá ilé ìwé gbogbo láti rí wí pé wọn mú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti o peregede fún àwọn ìdánwò náà

Comments are closed.

button