Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti gbéra lọ sí Ìlú Awka ti ṣe Olú ìlú ìpínlẹ̀ Anambra fun ṣíṣí àwọn àkànṣe iṣẹ́ .
Ní ìlú Akwa, ààrẹ Tinubu yóò sì àwọn àkànṣe iṣẹ́ ti ijọba gómìnà Chukwuma Soludo ti ṣe.
Àwọn akanse iṣẹ ti ààrẹ fẹ sí ní ìpínlẹ̀ Anambra nìyí; “Emeka Anyaoku Institute for International Studies and Diplomacy, Solution Fun City, Family Fun House, a Water Park, Amusement Park, Government House Mini City, Anambra Tower of Light, Monument of the Statues of (Five) Anambra Heroes”, abbl.
Gómìnà yóò wà fi ayẹyẹ àwẹ̀jẹ wẹ̀mu pari àbẹwò ààrẹ sì ipinlẹ náà láti bù ọlá fún ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ààrẹ Tinubu ní ìrètí wà pé yóò padà sí Abùjá ní òpin ohun gbogbo ní ọjọ́ Ọjọ́bọ̀.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san