Mínísítà fún Ìròyìn àti Àlàyé tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Idris, sọ pé ọnà látí wá ojútùú sí ìpèníjà Ààbò èyí tí kó nilo ìgbìyànjú púpọ̀ jú ìfẹ láti ọdọ àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sí ilú wọ́n.
Ọ̀gbẹ́ni Idris, ẹni tó sọ èyí ní àpéjọ àpérò kéje tí àwọn Mínísítà 2025 ní Abuja, Olú-ìlú Orílẹ̀-èdè, tún ṣé àkíyèsí pé ìṣàkóso Ààrẹ Tinubu tí ṣé ààbò ní pàtàkì ṣáájú òun kòún.
![]()
Àpéjọ yìí ṣé igbalaye pàtàkì fún àwọn Mínísítà látí ṣiṣẹ́ ìmúdójúìwọ̀n fún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lórí àwọn àṣeyọrí pàtàkì, àwọn iṣẹ́ àkànṣe àti àwọn ìtọ́sọ́nà àwọn ètò tí Mínísítà Ààbò àti Àyíká.
![]()
![]()
Látí ìbẹrẹ iṣẹ́ àkànṣe yí ní oṣù Kejì ọdún yìí, Ilé-iṣẹ́ ìròyìn àti Àlàyé tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí gbàlejò àwọn Mínísítà látí àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba oríṣi mẹjọ.
Comments are closed.