Take a fresh look at your lifestyle.

Fásítì Cairo Ni Ó Peregedé jùlọ Nípa Imo Ogún Ni Ilé Áfíríkà.

60

Níbi ikẹkọ nípa ètò ẹ̀kọ́ nípa ogún ni Fásítì Cairo, wọn ní Fásítì yìí lo Peregede jùlọ ni ilé Egypt àti kàkàkí Áfíríkà.

Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn ti sọ, wọn ní Fásítì Cairo ló gbé igbá oróke nípa ètò ògún àti àwọn ibi méwàá miran.

Wọn láàrin àwọn Fásítì ọgọrùn olè ni àádọta lágbayé Fásítì yìí lo fakọyo jùlọ

Àwọn alákòóso ilé ìwé gíga Cairo ni ,èyí o ṣe ṣe láì ṣe wí pé ifowosowopo tó wà láàrin àwọn òṣìṣẹ́ ati íwáàdí tó yanranti.

Comments are closed.

button