Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbákejì Ààrẹ Zimbabwe Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Mínísítà Ilẹ̀ Òkèèrè Tí Vatican

Lekan Orenuga

2,779

Ìgbákejì Ààrẹ Zimbabwe, Constantino Chiwenga, ṣé ìpàdé pẹ̀lú Mínísítà ile òkèèrè tí Vatican, Archbishop Paul Richard Gallagher, ní Rome ní Ọjọ́ Àbámẹ́ta.

‎ Ìpàdé náà dá lórí àwọn ìpèníjà ìṣèlú àti ètò ọrọ-àjé tí Zimbabwe, pẹ̀lú àwọn ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin Zimbabwe àti Ilé ìjọsìn Kátólìkì náà, ní pàápàá júlọ lórí ètò ẹ̀kọ́ àti ìlera.

‎ Gẹ́gẹ́bí àlàyé kán látí Vatican ṣé sọ́ pé àwọn ìjíròrò náà yóò tún kojú àwọn ètò ààbò orílẹ̀-èdè náà àti àgbáyé lápapọ̀, èyí tó ṣàfihàn ètò àlàáfíà lágbayé.

Comments are closed.

button