Take a fresh look at your lifestyle.

Ijoba Ebonyi Ṣé Ìdásílẹ̀ Àgbègbè Fún Àwọn Ilé-iṣẹ́ Túntún ‎

Lekan Orenuga

97

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi Francis Nwifuru tí bẹ̀rẹ̀ kíkọ àgbègbè ilé-iṣẹ́ kan ní ìpínlẹ̀ náà, Gúúsù ìlà òòrùn Nàìjíríà.

‎ Àgbègbè ilé-iṣẹ́ náà, èyítí o wà lẹgbẹẹ ilé-iṣẹ́ iṣelọpọ paipu tí ìpínlẹ̀ náà, yóò bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn òpópó-ònà tó dára pẹ̀lú ìpèsè iná mọnamọna àti omí ẹ̀rọ́ tó dára, ṣiṣẹ́ àtúnṣe àwọn ọnà, ìṣàkóso ìlọsíwájú àwọn idọti àti àtúnṣe àwọn ààbò àyíká.

‎ Nígbàtí o ṣiṣọ lójú iṣẹ́ àkànṣe náà ní ààyè náà ní Izhiangbo, Ìjọba ìbílẹ̀ Ohaukwu tí ìpínlẹ̀ náà, Gómìnà sọ pé àgbègbè ilé-iṣẹ́ dúró gẹ́gẹ́bí ẹrí sí àwọn ìpinnu rẹ̀ lórí isọdọtun Ọrọ-Àjé, ṣiṣẹda iṣẹ́, àti ìdàgbàsókè tó kún.

Comments are closed.

button