Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti gba àwọn adari agbaye nímọ̀ràn láti wà ní isokan, ní emi ìgboyà àti kí wọn ní ẹ̀mí ifaraji láti ṣàkóso ìṣòro oju ọjó lágbáyé tó n buru síi.
Ààrẹ sọ eyi ní ọjó ojoru nibi Ipade apero láti ori ero ayélujára lórí oju ọjó, ààrẹ jẹ kó di mímọ̀ pe orílè-èdè Nàìjíríà ma ri wípé wahala oju ọjó kò sakobá ba idagbasoke òrò ajé.
Agbateru Ipade náà ní àjọ United Nations Secretary ki-General António Guterres ati ààrẹ Brazil, Luiz Inacia Lula da Silva, ṣe papọ ní ọnà láti jẹ kí èròngbà oju ọjó agbaye tẹ síwájú latari ètò COP30 tó ní nbọ ti orile-ede Brasil máa gbalejo rẹ.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san