Take a fresh look at your lifestyle.

Falz Ṣetán Láti Gbé Àwo Orin Tuntun Elẹ́ẹ̀kẹfà Jáde

157

 

Akọrin tàkasùfé ọmọ Nàìjíríà, Folarin Falana ti ìnangi rẹ̀ ń jẹ́ Falz ti ṣetan láti gbé àwo orin rẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹfà jáde tó pè ní – “The Feast”ni Ọgbọnjọ́ oṣù karùn ún, ọdún 2025.

Nígbà ti o n sọ iroyin ayọ̀ náà fún àwọn ololufẹ rẹ, ó kọkọ dúpẹ́ lọ́wọ́ wọn fún ifarada wọn àti pé laipẹ ní ọjọ́ ti òun sọ orin náà yóò jáde.

 

Yàtọ̀ sì orin, Falz tún ń seré lori itage, o tilẹ jáde nínu eré kan ti wọn pè ní ” Ọkọ àti Iyawo àwọn ọjọ́ diẹ “ tó jáde ní ọdún 2016.

 

Ẹbùn pé o leè se orísìí ọ̀pọ̀ nǹkan jẹ kó gba ọpọ àmì ẹyẹ bíi; orín tó dára jùlọ ọdún, ti àmì ẹyẹ – City People Entertainment Awards ọdún 2016 abbl.

 

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button