Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò Ìsúná Owó Fún Ètò Ọ̀gbìn Ti Ọdún 2025 Ní Ìpínlẹ̀ Bauchi Kéré Jọjọ- Àwọn Àgbẹ̀ Obìnrin Ké Gbàjarè

103

Ìgbìmọ̀ tí ń wòye sí ètò ìsúná owó ní Ìpínlẹ̀ Bauchi ti korò ojú látàrí bí ètò ìsúná ètò ọ̀gbìn ọdún 2025 se kéré jọjọ

 

Adarí ìgbìmọ̀ náà Arábìnrin Tabawa Atiku ni ó sọ ọ̀rọ̀ náà nígbà tí ó ń bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ Ajé, ní Ìlú Bauchi

 

Ó wá pàrọwà sí ìjọba Ìpínlẹ̀ Bauchi láti se àfikún ètò is̀úná owó fún ètò ọ̀gbìn, èyí tí yóò tó ìdámẹ́wàá àpapọ̀ ètò ìsúná kí ó le è tán ìsòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ

 

 

Comments are closed.

button