Ẹgbẹ́ Tó N Sàkoso Ètò Nkọ ọ̀gbìn IITA Ṣe Ìdánilékòó Fún Aárùnlẹ́ẹ̀gbẹ́ta olè ọgọ́ta Àwon Ènìyàn Ni ìpínlẹ̀ Jigawa.
Ẹgbẹ́ IITA ní ìpínlẹ̀ Kano ti ṣe ètò ìdánilékòó nípa nkán ọ̀sìn fún àwọn ènìyàn Aárùnlẹ́ẹ̀gbẹ́ta olè ọgọ́ta àwọn ènìyàn ti ko pe ní Jigawa.
Nínú ifọrọwọrọ pẹlú ẹni tó ń wá ni ìṣàkóso Ìdánilékòó náà ni ojo ìṣẹgun, Ọ̀gbẹni Badamasi Muktar, so wí pé, pàtàkì Ìdánilékòó náà ni láti ni ibasepọ pẹlú ilé iṣé MasterCard.
Muktar sọ wí pé àwọn ṣe èyí láti mú inú àwọn ọdọ dù àti láti gbà wọn sí iṣé láwùjọ.
Ó ní pàápàá jùlọ ló àwọn ọdọ́ yóò ni anfààní láti da sí ètò ọrọ̀ aje Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ará ìdánilékòó náà ki ìdàgbàsókè baa le ba tile toko.
Suleiman Muhammad tó jẹ okan lára àwọn aláàbọ̀ ará to sí jé Eni ti o jẹ anfààní eto dupẹ ni orúkọ àwọn tókun fún anfààní nlá yìí