Àjọ tí wọn pẹ ni United Nations Population Fún (UNFPA) ni ọjọ̀bọ̀ ti fá àwọn ohun èlò fún ètò Ifetosomobibi fún ìjọba ìpínlẹ̀ Kano.
Dọ́kítà Audu Alayande, tó jẹ aṣojú fún Àjọ náà sọ wí pé oun mú àwọn elo náà wà fún lílò àti àlàáfíà àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Kano.
Alayande ni Àjọ UNFPA mọ nípa bí àwọn ènìyàn àti ilé ìwòsan ìjọba ó ṣe ni àwọn ohun èlò yìí, èyí l’ofa to àwọn fi wa.
Ó tún gbóríyìn fún ilẹ isé Gates Foundation bi wọn ṣe se àtìlẹ́yìn nlá láti pèsè àwọn ohun èlò tó to Mílíọ̀nù ọgbọn fún ìpínlẹ̀ Kano.
Kọmísọ́nà fún ètò ìlera, Dọ́kítà Abubakar Yusuf dupẹ lọwọ àjọ UNFPA fún atilẹyin àti mímú ìlérí wọn ṣẹ, látàrí bi wọn pèsè àwọn ohun èlò náà