Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ìtajà Di Títìpa Ní Ìpínlẹ̀ Kaduna Látàrí Ọjà Tí Ó Ti Bàjẹ́

132

Àjọ NAFDAC gbé ìgbésẹ̀ akin pẹ̀lú títi ilé ìpa-ọjà-mọ́ kan pa látàrí àwọn oúnjẹ àti ohun èlò míràn tí ó ti bàjẹ́, èyí tí ó tó mílíọ̀nù márùn-ún dín-lọ́gọ́rin náírà ní ìlú Kaduna

 

Shaba Muhammed tí ó jẹ́ adarí ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ àjọ náà síṣọ lójú ọ̀rọ̀ náà ní ọjọ ìṣẹ́gun ní ìlú Kaduna

 

Ó sàlàyé pé ilé ìpọjàmọ́ náà wà ní òpópónà Bayajidda , oju ọna Ogbomọsọ tuntun, ìpínlẹ̀ Kaduna. Ó tẹ̀síwájú pé ìwádìí ń lọ lọ́wọ́, tí àrídájú sì wà pé àwọn tí aje ọ̀rọ̀ náà bá sí mọ́ lórí yóò fi imú kó ata òfin, èyí tí yóò jẹ́ ìkìlọ̀ fún àwọn tí ó kù

 

Comments are closed.

button