Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Obìnrin Ẹgbẹrun Márùn Olè Ní Ìgbà.

164

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano Abba Kabir Yusuf tí ṣe Ìrànlọ́wọ́ fún àwọn obìnrin ẹgbẹrun márùn ole ìgbà ni ìpínlẹ̀ náà.

Ó ní èyí wa lára Àdéhùn rẹ láti ran àwọn ènìyàn lọwọ.

Gómìnà Yusuf tun fi n da àwọn lójú wí pé oun ṣe bèrè iṣé ni ìpínlẹ̀ náà ni wí  pé ki àwọn ènìyàn fi òkan balẹ.

Ó ni àwọn ètò yìí yóò pọ láàrin àwọn Obìnrin àti àwọn ọdọ.

Gómìnà Yusuf ni láti oṣù kàrún ọdún 2024 ti ètò náà ti bèrè ètò náà àwọn ti ṣe Ìrànlọ́wọ́ fún àwọn obìnrin lati ọ̀dọ́ to le ni ẹgbẹrun lọnà ogoji.

Ó ní èròngbà oun ní láti ran àwọn tó bá ní ẹbùn lọwọ àti àwọn ti o le ronú fún ìdàgbàsókè ìpínlẹ̀.

Ó rọ àwọn àwọn tó jẹ anfààní náà láti o daradara.

Comments are closed.

button