Ìpínlẹ̀ Kaduna, lábẹ́ àkóso Gómìnà Uba Sani ti gbáradì láti gbógunti jíjẹ ìjẹkúje àti àwọn oúnjẹ tí kò se ara lóòre láwùjọ
Alágba ìgbìmọ̀ tí ó ń mójútó ọ̀rọ̀ oújẹ ní ìpínlẹ̀ kaduna, Mukhtar Ahmed ni ó sọ ọ̀rọ̀ náà níbi ìpàdé ọlọ́jọ́ kan ti o waye lori ọ̀rọ̀ oúnjẹ ní Ọjọ́bọ, ní ìlú Kaduna
Ó fi àrídájú hàn pé ìjọba ìpínlẹ̀ náà ti gbe ìgbésẹ̀ lati tan ìsòro jíjẹ àwọn oúnjẹ ti ko se ara loore