Mínísítà fún ètò ààbò, Dókítà Bello Muhammed Matawalle, tí dúpẹ́ fún Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu, fún ìgbésẹ tó ṣé pàtàkì látí ríi dájú pé sisán owó oṣù àwọn ológun ní kíákíá pẹ̀lú ajẹ́-sílẹ oṣù mẹ́ta.
O tún dúpẹ́ lọ́wọ́ Ààrẹ fún owó àwọn òṣìṣẹ́ fẹyinti àti àwọn ẹ̀tọ́ mìíràn tí àwọn Òṣìṣẹ́ fẹyinti Ológun.
Ọrọ̀ náà ló wáyé nípasẹ̀ Olùdarí Àlàyé àti Ìbáṣepọ̀ tí Ilé-iṣẹ́ Ológun, Henshaw Ogubike sọ pé Dókítà Matawalle fí ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé owó náà tí bẹrẹ̀ síi wọlé titi dórí tí oṣù mẹ́ta tí wọ́n jẹ́ àwọn ológun.
Comments are closed.