Take a fresh look at your lifestyle.

Látàrí Ètò Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ondo: Àjọ Elétò Ìdìbò Pàrowà Sí Àwọn Oníròyìn Láti Jìnà Sí Ìròyìn Òfegé

133

Àjọ Elétò ìdìbò ti pàrowà sí àwọn oníròyìn láti fi òpin sí ìtànkálẹ̀ ìròyìn òfegé èyí tí ó se é ṣe kí ó wáyé síwájú, lásìkol àti lẹ́yìn ètò ìdìbò sí ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Eko

Ọ̀gbẹ́ni Sam Olumekun ni o fi ọrọ naa léde níbi àpérò kan ti o wáyé pẹ̀lú àwọn oníròyìn ní ìlú Akure, Ìpínlẹ̀ Ondo nibi ti ó ti gba àwọn oníròyìn níyànjú láti kó ipa tí ó yanjú fún ìkẹṣẹjari ètò ìdìbò náà

Ó wá rọ àwon oniroyin lati wà ní ojú ní alákàn fi ń sọri, kí wọ́n sì sàgbéyẹ̀wò ìròyín kí wọ́n tó fi léde kí ó ma ba à sin àwọn ará ìlú darí.

 

Comments are closed.

button