Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Ivory Coast Se Àjoyọ̀ Ọjọ́ Àyájọ́ Agbègbè Ìlú Wọn

62

 

Ni ọdọọdún, ènìyàn ilu Abidjis ti won n gbe ni guusu ìlà oorun abule Yaobou a máa se ajoyọ idasile agbegbe wọn.

Ayẹyẹ náà ni won n pé ni ọdún ‘dipri’
Ni ede ibilẹ̀, ‘di’ tumo sí omi àti pé ‘pri’ náà túmọ̀ sí ìgbéra pá. Àwọn ẹbi a sì máa seé. Koffi N’guessan ni wọn sì mú ni ọdún yìí.

Àwọn ènìyàn Abidji ti Yaobou jẹ ti ìdílé
Akan. Wọn ṣẹ̀ wá láti orílẹ̀-èdè Ghana.

Nígbà ti wọn ṣá fún ogun, wọn tun ba ara wọn niwaju odo Comoé. Okan ninu wọn fi ara rè se ìrúbo fún àwọn yòókù lati koja.

Ọdún náà jẹ́ ọ̀nà lati fi sayajo iṣẹlẹ ti idasilẹ. Àwọn eniyan Abidjis a máa wọ Aṣọ funfun tó túmọ sí mimọ, wọn a sì fi
kaolin pa ojú, eyi tó túmọ sí ìwà ìrẹlẹ àti àlàáfíà.

Ọdún náà ni wọn se ni ibẹrẹ oṣù kẹrin ọdún yìí to tun se pẹ̀kírẹ̀kí pẹlu oṣù òṣùpá Kalẹnda ti Abidji to jẹ odun tuntun ni ti aṣa awọn Abidji.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.